Mọ iye ọdún tó ṣeéṣe kí o lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé iye ọdún tó ṣeéṣe kí gbogbo ènìyàn yóò lò láyé ti fi ọdún méje pọ̀ si láti 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè tí o ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Fo Móríwú kọjá kí o tẹ̀síwájú

Móríwú

  • Àwọn afurasí apaayan mẹta kọ ẹyin láti ya àwòrán
  • Àwọn afurasí mẹ́ta kọ ẹyin láti ya àwòrán
  • Taofeek Adegoke wọ asọ toketilẹ alawọ buluu ati fila asọ oke buluu, o so ọwọ rẹ mejeeji papọ
  • Ọkunrin to bọ lọwọ ajinigbe wọ asọ toke tilẹ ati fila alawọ ewe
  • Agubanirọ naa wọ asọ buluu, da sikafu bo ori de ọrun, o lo awo dudu, fi nnkan we ẹnu
  • Danladi wọ asọ ibilẹ alawọ buluu ati fila rẹ
  • Amina Eleha wọ kaba aláwọ̀ búlúù, ó sì ṣe irun dídì gbọọrọ
  • Gomina Aiyedatiwa wọ aṣọ shaati funfun, ó dé fìlà aláwọ̀ buluu
  • Murphy Ray Eyiwumi wọ aṣọ agbada aláwọ̀ Pọpu, ó dé fìlà Goolu, ó fi ẹfun kun orí rẹ
  • Ọkunrin kan to wọ asọ shaati polo alawọ buulu n nawọ si ọkankan
  • Peter Obi wọ asọ toke tilẹ dudu ati fila rẹ, o na ọwọ rẹ mejeeji soke lati fi se apejuwe
  • Gbadebo Rhodes-Vivour wọ asọ toke tilẹ ati fila alawọ funfun, o ka ọwọ rẹ mejeeji mọ igba aya

Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ