Coronavirus updates: Bá wo ni coronavirus ṣe ń tàn kálẹ̀ ní àyíká wa?

Àkọlé fídíò, Bá wo ni coronavirus ṣe ń tàn kálẹ̀ ní àyíká wa?
Published

Ba wo gan an ni aarun coronavirus ṣe tan kaakiri layika wa?

Aarun coronavirus lagbara lati ran lati ibi kan si omiiran.

Iwadii ti fihan pe ida ọgọrin ninu ọgọrun awọn to laarun coronavirus ni kii ni ami tabi apẹrẹ to le fihan pe wọn ti laarun naa.

Iru awọn eeyan yii lawọn oloyinbo n pe ni ''Asymptomatic.''

Ewu to wa nibẹ ni pe iru awọn eeyan yii le ko aarun covid-19 ran ọpọlọpọ eniyan.

Ajọ WHO ni titakete si ara ẹni lo ṣe pataki bayii lati dena aarun covid-19.