Mò ń fi lẹ̀kẹ̀ ya àwọnran láti jèrè ǹkan méjì - Olaniyi Olaniyan

Àkọlé fídíò, Mò ń fi lẹ̀kẹ̀ ya àwọnran láti jèrè ǹkan méjì - Olaniyi Olaniyan
Published

Botilẹ jẹ pe Olaniyi Sunday Olaniyan bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àwòràn yíyà rẹ̀ ni ibi kékére sùgbọ̀n lónìí, ó jẹ́ ọkan lára àwọn to ń ṣe ǹkan àrà ọ̀tọ̀. Ọ́ ní yíya àwọnran pẹ̀lú ìlẹ̀kẹ̀ wẹ́wẹ́ jẹ ohun to gbà sùúrù gídi síbẹ̀ ó yàn láàyò láti yàtọ láàrin akẹgbẹ́ rẹ̀.