Sagbokoji, ìlú tó sún mọ́ ọ̀làjú pẹ́kípẹ́kí ṣùgbọ́n tí iná ẹ̀lẹ́ńtíríkì kò sí láti ọgọ́ọ̀rún ọdún
Published
Awọn agba bọ, wọn ni nibi ti eeyan kan ti n sunkun airi eyin ni ẹnikan n sun airi ete bo tirẹ. Eyi ni ọrọ to ṣe kongẹ awọn eeyan ileto Sagbokodji ni ipinlẹ Eko.
Lati nnkan bi ọgọrun ọdun ti ileto naa ti wa, ko si ina ẹlẹntiriiki ni ilu naa. Bẹẹ si niyi, ilu ti a n wi yii ko jinna si awọn ilu nla ati ibugbe awọn eeyan jankanjankan ni ipinlẹ Eko.
Ẹ gbọ naa, bawo ni ọbọ ṣe ṣe ori ti inaki o ṣe?
- Mi ò ní ìyàwó nílé, àmọ́ mo ní ọmọ tó pọ̀-Saheed Oṣupa
- Shuaib ní wọ́n pa irọ́ mọ́ òun láti tako Sẹ́nétọ̀ Adeleke ní ilé ẹjọ́
- Facebook gbégilé àwọn ojú òpó ayédèrú
- Ẹ wo Pelumi tó fẹ́ lọ ṣojú Naijiria ni orílẹ̀èdè Hungary lọ́dún yìí
- ASUU ń lérí ìyanṣẹ́lódì lórí ọwọ́jà ìjínigbé lórílẹ̀èdè Nàìjíríà
- Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí ajínigbé 93, àti ìbọn 'AK47' márùndínlógójì
- 60,000 àwakọ ló ń lo iwé ìrinà ọ̀kọ̀ tí kò k'oju oṣùwọn ní ìpínlẹ̀ Eko - FRSC
- Kí ló dé tí ìjọba Èkìtì ń fí àwọn òṣìṣẹ́ ṣé ''helo-helo testing"?