Ǹjẹ́ èèyàn leè kó àrùn Corovirus láti ara ẹ̀fọn?

Àkọlé fídíò, Ǹjẹ́ èèyàn leè kó àrùn Corovirus láti ara ẹ̀fọn?
Published

Lẹyin ti arun Coronavirus ti kọlu miliọnu meji eeyan kaakiri agbaye, ti iye awọn to ni arun ọhun si n pọ si lojojumọ.

Awọn kan ti wa n sọ pe ẹfọn le gbe arun naa lati ara ẹnikan si ẹlomiran.

Ṣugbọn ajọ to n risi eto ilera lagbaye, WHO ti sọ pe eeyan lee ko lee arun naa lati ara ẹfọn.

Ẹ wo fidio yii fun ẹkunrẹrẹ.