Àwọn ọníṣẹ́ ọwọ́ wọ̀nyí ti gbowó iṣẹ́ àmọ́ Coronavirus ò jẹ́ kí n ṣisé owó tí wọ́n gbà
Published
Lati igba ti ajakalẹ arun COVID-19 ti rapala wọ orilẹede Naijiria, oniruuru ipa lo ti ni.
Lara awọn ipa to ni ni bi awọn eeyan to n ṣe awọn iṣẹ kan ko ṣe lee ṣe iṣẹ mọ nitori ipa ti o ni lori iṣẹ wọn.
Ko si idi meji ju wi pe, arun yii ti jẹ ko di mimọ fun gbogbo mutumuwa pe oun ko ni faramọ aṣepọ awọn eeyan ni fifarakanra, eyi to si jẹ pe akoba ni fun awọn iṣẹ kan nitori aṣepọ bẹẹ lo n mu ọrọ aje ya fun wọn.
- Alfa Babatunde Sotitobire tún fojú balé ẹjọ́ lọ́nìí, bàbá ọmọ jẹri níwájú adájọ́
- Ohun mẹ́fà tí àgbáyé kò mọ̀ nípa Majek Fashek tó d'olóògbé nìyí
- Ọwọ́ ọlọpàá tí tẹ ọ̀kan nínú àwọn ọ̀daràn tó ṣekú pa Uwaila
- ₦35,000 ni mò ń gbà bíi Adelé ọba, kò sí ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ - Adelé Olúbọ̀rọ̀pa
- Ẹ wo ọmọ Yorùbá kan tó ru àrùn coronavirus là nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì
- Ìlú yóò le, ọmọ le kú, àìsàn yóò pọ̀ bí eégún kò bá jáde nílùú Ibadan - Olóòlù