Coronavirus in Nigeria: Ìwádìí fihàn pé ọ̀pọ̀ aráàlú ni kò gbà pé àrùn Covid-19 wà
Published
Arun Coronavirus ti n ba gbogbo agbaye finra lati bii osu meje sẹyin, ti ọpọ eeyan si ti jade laye lati ipasẹ arun naa.
Amọ iwadii ikọ iroyin BBC ni orilẹede Naijiria fihan pe ọpọ awọn araalu naa ni ko gbagbọ pe arun kankan wa, to n jẹ Coronavirus.
Awọn eeyan to ba wa sọrọ ni awọn ti wọn ko sile iyasọtọ kan n mu ọti, jo, ti wọn si n se ariya ni.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wọ́n fi ikú Tunde Braimoh dá wa lóró ni o - Ẹbí pariwo
- Ìtàn ayé Henry Fajemirokun, olówó tó fi owó mọ Olúwa àti ènìyàn
- Báwo ni Coronavirus ṣe n tànkálẹ̀ l'Afrika?
- Ó ṣeéṣe kí ènìyàn 12,000 máa kú lójoojúmọ́ lẹ́yìn Covid-19
- Orílẹ̀-èdè mẹ́wàá tí ẹgbẹ́ alákatakítí Islamic State n fínna mọ́ ní àgbáyé
- N kò gba ₦4bn lọ́wọ́ Magu, ẹ má ró àjẹbánu mọ́ mi láṣọ - Osinbajo pariwo
- Mi ò tíì gba ìwé ìfitónilétí pé wọ́n fẹ́ yọ mí nípò igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Ondo- Agboola Ajayi
Bi o tilẹ jẹ pe ẹgbẹrin eeyan to ko arun naa, lo wa nibudo ti wọn ti n tọju awọn alarun Coronavirus nilu Eko, sibẹ ọkunrin kan ni ọgbọn eeyan gbọdọ ku ni ẹgbẹ oun, ki oun to lee gbagbọ pe arun Coronavirus wa.
Bi iwadii naa se lọ ree: