Àwọn onímọ̀ ọpọlọ ní to bá gbé ìgbésẹ̀ yìí, aṣeyege dájú ní ìdánwò

Àkọlé fídíò, Àwọn onímọ̀ ọpọlọ ní to bá gbé ìgésẹ̀ yí, aṣeyege dájú ní ìdánwò
Published

Iroyin ibanujẹ kan ni ọjọ Aje wipe ọmọkunri kan, Segun mu òògùn apakòkòrò tórí máàkì 167 nínú JAMB, idanwo si ile iwe giga ni Naijiria. Ṣugbọn awọn onimọ nipa bi ọpọlọ ṣe n ṣiṣẹ ni awọn ọna kan wa ti eniyan fi le yago fun ijakulẹ ninu idanwo.

Awọn iròyìn mìíran tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ si: